1. Pet 3:21 YCE

21 Apẹrẹ eyiti ngbà nyin là nisisiyi pẹlu, ani baptismu, kì iṣe ìwẹ ẽri ti ara nù, bikoṣe idahùn ọkàn rere sipa Ọlọrun, nipa ajinde Jesu Kristi:

Ka pipe ipin 1. Pet 3

Wo 1. Pet 3:21 ni o tọ