1. Pet 4:13 YCE

13 Ṣugbọn niwọnbi ẹnyin ti jẹ alabapin ìya Kristi, ẹ mã yọ̀, ki ẹnyin ki o le yọ̀ ayọ̀ pipọ nigbati a ba fi ogo rẹ̀ hàn.

Ka pipe ipin 1. Pet 4

Wo 1. Pet 4:13 ni o tọ