1. Pet 4:17 YCE

17 Nitoriti ìgba na de, ti idajọ yio bẹ̀rẹ lati ile Ọlọrun wá: bi o ba si tète ti ọdọ wa bẹ̀rẹ, opin awọn ti kò gbà ihinrere Ọlọrun gbọ́ yio ha ti ri?

Ka pipe ipin 1. Pet 4

Wo 1. Pet 4:17 ni o tọ