1. Pet 4:6 YCE

6 Nitori eyi li a sá ṣe wasu ihinrere fun awọn okú, ki a le ṣe idajọ wọn gẹgẹ bi enia nipa ti ara, ṣugbọn ki nwọn ki o le wà lãye si Ọlọrun nipa ti ẹmí.

Ka pipe ipin 1. Pet 4

Wo 1. Pet 4:6 ni o tọ