Jud 1:11 YCE

11 Egbé ni fun wọn! nitoriti nwọn ti rìn li ọ̀na Kaini, nwọn si fi iwọra súré sinu ìṣina Balaamu nitori ère, nwọn si ṣegbé ninu iṣọtẹ̀ Kora.

Ka pipe ipin Jud 1

Wo Jud 1:11 ni o tọ