Ẹkún Jeremáyà 1:11 BMY

11 Àwọn ènìyàn rẹ̀ ń kérorabí wọ́n ti ń wá oúnjẹ;wọ́n fi ohun ìní wọn se pàsípààrọ̀ oúńjẹláti mú wọn wà láàyè.“Wò ó, Olúwa, kí o sì rò ó,nítorí a kọ̀ mí sílẹ̀.”

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 1

Wo Ẹkún Jeremáyà 1:11 ni o tọ