Ẹkún Jeremáyà 1:13 BMY

13 “Ó rán iná láti òkèsọ̀kalẹ̀ sínú egungun ara mi.Ó dẹ àwọ̀n fún ẹsẹ̀ mi,ó sì yí mi padà.Ó ti pa mí láramó ń kú lọ ní gbogbo ọjọ́.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 1

Wo Ẹkún Jeremáyà 1:13 ni o tọ