11 Ojú mi kọ̀ láti sunkún,mo ń jẹ ìrora nínú mi,mo tú ọkàn mi jáde sí ilẹ̀nítorí a pa àwọn ènìyàn mí run,nítorí àwọn ọmọdé àti ọmọ ọwọ́ ń kúní òpópó ìlú.
Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 2
Wo Ẹkún Jeremáyà 2:11 ni o tọ