45 Ó ti sọ wá di èérí àti ààtànláàrin orílẹ̀ èdè gbogbo.
46 “Gbogbo àwọn ọ̀tá wa ti la ẹnu wọngbòòrò sí wa.
47 Àwa ti jìyà àti ìparun,nínú ìbẹ̀rù àti ewu.”
48 Omijé ń ṣàn ní ojú mi bí odònítorí a pa àwọn ènìyàn mi run.
49 Ojú mi kò dá fún omijé,láì sinmi,
50 títí ìgbà tí Olúwa síjú wolẹ̀láti òkè ọ̀run tí yóò sì rí i.
51 Ohun tí mo rí mú ìbẹ̀rù wá ọkàn minítorí gbogbo àwọn obìnrin ìlú mi.