7 Ó ti tì mí mọ́lé nítorí náà n kò le è sálọ;ó ti fi ẹ̀wọ̀n mú mi mọ́lẹ̀
8 Pàápàá nígbà tí mo ké fún ìrànlọ́wọ́,ó kọ àdúrà mi.
9 Ó fi búlọ́kù òkúta dí ọ̀nà mi;ó sì mú ọ̀nà mi wọ́
10 Bí i béárì tí ó dùbúlẹ̀,bí i kìnnìún tí ó sá pamọ́.
11 Ó wọ́ mi kúrò ní ọ̀nà, ó tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ó fi mi sílẹ̀ láì sí ìrànlọ́wọ́.
12 Ó fa ọfà rẹ̀ yọó sì fi mí sohun ìtafàsí.
13 Ó fa ọkàn mí yapẹ̀lú ọfà nínú àkọ̀ rẹ̀.