Hágáì 1:11 BMY

11 Mo sì ti pe ọ̀dá sórí ilẹ̀ àti sórí awọn òkè-ńlá, sórí ọkà àti sórí wáìnì tuntun, sórí òróró àti sórí ohun ti ilẹ̀ ń mú jáde, sórí ènìyàn, sórí ẹran àti sórí gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ yín.”

Ka pipe ipin Hágáì 1

Wo Hágáì 1:11 ni o tọ