Hágáì 1:8 BMY

8 Ẹ gun orí àwọn òkè ńlá lọ, kí ẹ sì mú igi wá pẹ̀lú yín. Kí ẹ sì kọ́ ilé náà, kí inú mi bà leè dùn sí i, kí a sì yín mí lógo,” ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Hágáì 1

Wo Hágáì 1:8 ni o tọ