Jóẹ́lì 2:13 BMY

13 Ẹ sì fa ọkàn yín ya,kì í sì í ṣe aṣọ yín,ẹ sì yípadà sí Olúwa Ọlọ́run yín,nítorí tí o pọ̀ ní oore ọ̀fẹ́,ó sì kún fun àánú, ó lọ́ra láti bínú,ó sì ṣeun púpọ̀, ó sì ronúpìwàdà láti ṣe búburú.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 2

Wo Jóẹ́lì 2:13 ni o tọ