Jóẹ́lì 3:17 BMY

17 “Nígbà náà ni ẹ̀yin yóò mọ̀ pé, èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín,tí ń gbé Ṣíónì òkè mímọ́ mi.Ìgbà náà ni Jérúsálẹ́mù yóò jẹ́ mímọ́;àwọn àlejò kì yóò sì kó o mọ́.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 3

Wo Jóẹ́lì 3:17 ni o tọ