Jóẹ́lì 3:19 BMY

19 Ṣùgbọ́n Éjíbítì yóò di ahoro,Édómù yóò sì di aṣálẹ̀ ahoro,nítorí ìwà ipá tí a hù sì àwọn ọmọ Júdà,ní ilẹ̀ ẹni tí wọ́n ti ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 3

Wo Jóẹ́lì 3:19 ni o tọ