Málákì 1:4 BMY

4 Édómù lè wí pé, “Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a run wá, àwa yóò padà wá, a ó sì tún ibùgbé náà kọ́.”Ṣùgbọ́n èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ ogun wí pé: “Àwọ́n lè kọ́, ṣùgbọ́n èmi yóò wó palẹ̀. Wọn yóò sì pè wọ́n ní Ilẹ̀ Búburú, àwọn ènìyàn tí wọ́n máa ń wà ní ìbínú Olúwa.

Ka pipe ipin Málákì 1

Wo Málákì 1:4 ni o tọ