Málákì 1:8 BMY

8 Nígbà tí ẹ̀yin mú afọ́jú ẹran wá fún ìrúbọ, ṣé ìyẹn kò ha burú bí? Nígbà tí ẹ̀yin fi amúkùnún àti aláìsàn ẹran rúbọ, ṣé ìyẹn kò ha bògìrì bí? Ẹ dán an wò, ẹ fi wọ́n rúbọ sí àwọn baálẹ̀ yín! Ṣé inú rẹ̀ yóò dùn sí yín? Ṣé yóò gbà yín?” ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí.

Ka pipe ipin Málákì 1

Wo Málákì 1:8 ni o tọ