Málákì 3:12 BMY

12 “Nígbà náà ni gbogbo orílẹ̀ èdè yóò sì pè yín ni alábùkún fún, nítorí ti yín yóò jẹ́ ilẹ̀ tí ó wuni,” ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí.

Ka pipe ipin Málákì 3

Wo Málákì 3:12 ni o tọ