Míkà 2:12 BMY

12 “Èmi yóò kó gbogbo yín jọ, ìwọ Jákọ́bù;Èmi yóò gbá ìyókù Ísírẹ́lì jọ.Èmi yóò kó wọn jọ pọ̀ gẹ́gẹ́ bí àgùntàn nínú agbo ẹran,gẹ́gẹ́ bí ọ̀wọ́ ẹran nínú agbo wọn,ibẹ̀ yóò sì pariwo nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn.

Ka pipe ipin Míkà 2

Wo Míkà 2:12 ni o tọ