Míkà 2:13 BMY

13 Ẹni tí ó ń fọ ọ̀nà yóò lọ sókè níwájú wọn;Wọn yóò fọ láti ẹnu-bodè, wọn yóò sì jáde lọ.Àwọn ọba wọn yóò sì kọjá lọ níwájú wọn, Olúwa ni yóò sì ṣe olórí wọn.”

Ka pipe ipin Míkà 2

Wo Míkà 2:13 ni o tọ