Náhúmù 1:5 BMY

5 Àwọn òkè ńlá wárìrì níwájú rẹ̀,àwọn òkè kéékèèkéé sì di yíyọ́,ilẹ̀ ayé sì jóná níwájú rẹ̀,àní ayé àti gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀.

Ka pipe ipin Náhúmù 1

Wo Náhúmù 1:5 ni o tọ