Náhúmù 1:6 BMY

6 Ta ni ó lé dúró níwájú ìbínú rẹ̀?Ta ni ó lé faradà gbígbóná ìbínú rẹ̀?Ìbínú rẹ̀ tú jáde bí iná;àwọn àpáta sì fọ́ túútúú níwájú rẹ̀.

Ka pipe ipin Náhúmù 1

Wo Náhúmù 1:6 ni o tọ