Rúùtù 1:22 BMY

22 Báyìí ni Náómì ṣe padà láti Móábù pẹ̀lú Rúùtù, ará Móábù ìyàwó ọmọ rẹ̀. Wọ́n gúnlẹ̀ sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ní ìbẹ̀rẹ̀ ìkórè ọkà bálì.

Ka pipe ipin Rúùtù 1

Wo Rúùtù 1:22 ni o tọ