Rúùtù 1:3 BMY

3 Ní àsìkò tí wọ́n ń gbé ibẹ̀, Elimélékì, ọkọ Náómì kú, ó sì ku òun (Náómì) pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ ọkùnrin méjèèjì.

Ka pipe ipin Rúùtù 1

Wo Rúùtù 1:3 ni o tọ