Rúùtù 2:8 BMY

8 Nígbà náà ni Bóásì sọ fún Rúùtù pé, “Gbọ́ ọmọbìnrin mi, má ṣe lọ sí oko mìíràn láti ṣa ọkà, má sì ṣe kúrò ní ibi. Dúró níbí pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́-bìnrin mi.

Ka pipe ipin Rúùtù 2

Wo Rúùtù 2:8 ni o tọ