Rúùtù 3:18 BMY

18 Náómì sì wí fún-un pé, “Dúró, ọmọbìnrin mi títí tí ìwọ yóò fi mọ bí ohun gbogbo yóò ti rí. Nítorí pé ọkùnrin náà kò ní sinmi títí tí ọ̀rọ̀ náà yóò fi yanjú lónìí.”

Ka pipe ipin Rúùtù 3

Wo Rúùtù 3:18 ni o tọ