Rúùtù 4:17 BMY

17 Àwọn obìnrin àdúgbò sì wí pé, “A bí ọmọkùnrin kan fún Náómì.” Wọ́n sì pe orúkọ rẹ̀ ní Óbédì. Òun sì ni baba Jésè tí í ṣe baba Dáfídì.

Ka pipe ipin Rúùtù 4

Wo Rúùtù 4:17 ni o tọ