Rúùtù 4:3 BMY

3 ó sì sọ fún ìbátan rẹ̀ náà pé, “Arábìnrin Náómì tí ó dé láti ilẹ̀ Móábù fẹ́ ta ilẹ̀, èyí tí ó ṣe ti arákùnrin wa, Elimélékì.

Ka pipe ipin Rúùtù 4

Wo Rúùtù 4:3 ni o tọ