Rúùtù 4:5 BMY

5 Nígbà náà ni, Bóásì sọ wí pé, “Bí ìwọ bá ti ra ilẹ̀ náà lọ́wọ́ Náómì àti lọ́wọ́ Rúùtù ará Móábù, ìwọ gbọdọ̀ fẹ opó ọkùnrin náà, kí orúkọ ọkùnrin tí ó kú náà má ba à parẹ́ pẹ̀lú ohun ìní rẹ̀ àti kí o le è bímọ ní orúkọ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Rúùtù 4

Wo Rúùtù 4:5 ni o tọ