Sefanáyà 2:10 BMY

10 Èyí ni ohun tí wọn yóò gbà padà nítorí ìgbéraga wọn,nítorí wọ́n kẹ́gàn, wọn sì ti fi àwọn ènìyàn Olúwa alágbára ṣe ẹlẹ́yà.

Ka pipe ipin Sefanáyà 2

Wo Sefanáyà 2:10 ni o tọ