1 Jòhánù 1:2 BMY

2 Ìyè náà sì ti farahàn, àwa sì ti rí i, àwa sì ń jẹ́rí, àwa sì ń sọ ti ìyè àìnípẹ̀kun náà fún yín, tí ó ti ń bẹ lọ́dọ̀ Baba, tí ó sì farahàn fún wa.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 1

Wo 1 Jòhánù 1:2 ni o tọ