1 Jòhánù 1:5 BMY

5 Èyí sì ni iṣẹ́ tí àwa ti gbọ́ lẹ́nu rẹ tí àwa sì ń jẹ́ fún yín: pé ìmọ́lẹ̀ ni Ọlọ́run; ní ọ̀dọ̀ rẹ̀ kò sì òkùnkùn rárá.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 1

Wo 1 Jòhánù 1:5 ni o tọ