1 Jòhánù 1:7 BMY

7 Ṣùgbọ́n bí àwa bá ń rìn nínú ìmọ́lẹ̀, gẹ́gẹ́ bí òun ti ń wà nínú ìmọ́lẹ̀, àwa ní ìdàpọ̀ pẹ̀lú ara wa, àti pé ẹ̀jẹ̀ Jésù Kírísítì, Ọmọ rẹ̀, wẹ̀ wá nù kùrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ gbogbo.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 1

Wo 1 Jòhánù 1:7 ni o tọ