1 Jòhánù 3:16 BMY

16 Nípa èyí ni àwa mọ ìfẹ́ nítorí tí ó fi ẹ̀mí rẹ̀ lélẹ̀ fún wa: ó sì yẹ kí àwa fi ẹ̀mí wa lélẹ̀ fún àwọn ará.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 3

Wo 1 Jòhánù 3:16 ni o tọ