1 Jòhánù 3:4 BMY

4 Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń dẹ́ṣẹ̀, ó ń rú òfin pẹ̀lú: nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ni rírú òfin.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 3

Wo 1 Jòhánù 3:4 ni o tọ