1 Jòhánù 3:8 BMY

8 Ẹni tí ó ba ń dẹ́ṣẹ̀ tí èṣù ni; nítorí láti àtètèkọ́ṣe ni Èṣù ti ń dẹ́ṣẹ́. Nítorí èyí ni Ọmọ Ọlọ́run ṣe farahàn, kí o lè pa iṣẹ́ Èṣù run.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 3

Wo 1 Jòhánù 3:8 ni o tọ