1 Jòhánù 4:1 BMY

1 Olùfẹ́, ẹ má ṣe gba gbogbo ẹ̀mí gbọ́, ṣùgbọ́n ẹ dán àwọn ẹ̀mí wò bí wọn ba ń ṣe tí Ọlọ́run: nítorí àwọn wòlíì èké púpọ̀ tí jáde lọ sínú ayé.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 4

Wo 1 Jòhánù 4:1 ni o tọ