1 Jòhánù 4:13 BMY

13 Nípa èyí ni àwa mọ̀ pé àwa ń gbé inú rẹ̀, àti Òun nínú wa, nítorí tí ó ti fi Ẹ̀mí rẹ̀ fún wa.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 4

Wo 1 Jòhánù 4:13 ni o tọ