1 Jòhánù 4:16 BMY

16 Báyìí ni àwa mọ̀, tí a sì gba ìfẹ́ tí Ọlọ́run ní sí wa gbọ́.Ìfẹ́ ni Ọlọ́run; ẹni tí ó bá sì ń gbé inú ìfẹ́ ó ń gbé inú Ọlọ́run, àti Ọlọ́run nínú rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 4

Wo 1 Jòhánù 4:16 ni o tọ