1 Jòhánù 4:18 BMY

18 Ìbẹ̀rù kò sí nínú ìfẹ́; ṣùgbọ́n ìfẹ́ tí ó pé ń lé ìbẹ̀rù jáde; nítorí tí ìbẹ̀rù ni ìyà nínú. Ẹni tí ó bẹ̀rù kò pé nínú ìfẹ́.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 4

Wo 1 Jòhánù 4:18 ni o tọ