1 Jòhánù 4:3 BMY

3 Gbogbo ẹ̀mí tí kò si jẹ́wọ́ pé Jésù Kírísítì wà nínú ara, kì í ṣe tí Ọlọ́run: èyí sì ni ẹ̀mí aṣòdì-sí-kírísítì náà, tí ẹ̀yin ti gbọ́ pé ó ń bọ̀, àti nísinsin yìí ó sì tí de sínú ayé.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 4

Wo 1 Jòhánù 4:3 ni o tọ