1 Jòhánù 5:11 BMY

11 Ẹ̀rí náà sì ni èyí pé Ọlọ́run fún wa ní ìyè àìnípẹ̀kun, ìyè yìí sì ń bẹ nínú Ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Jòhánù 5

Wo 1 Jòhánù 5:11 ni o tọ