1 Tẹsalóníkà 1:9 BMY

9 Ṣe ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí i ròyìn fún wa bí ẹ ti gbà wá lálejò. Wọ́n ròyìn fún wa pẹ̀lú pé, ẹ ti yípadà kúrò nínú ìbọ̀rìṣà àti wí pé Ọlọ́run alààyè nìkan ṣoṣo ni ẹ ń sìn.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 1

Wo 1 Tẹsalóníkà 1:9 ni o tọ