1 Tẹsalóníkà 5:10 BMY

10 Jésù kú fún wa kí a lè ba à gbé títí láéláé. Èyí yóò rí bẹ́ẹ̀ yálà a sùn tàbí a wà láàyè pẹ̀lú rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 5

Wo 1 Tẹsalóníkà 5:10 ni o tọ