1 Tẹsalóníkà 5:11 BMY

11 Nítorí náà, ẹ máa gba ara yín níyànjú, kí ẹ sì máa gbé ara yín ró, gẹ́gẹ́ bí ẹ ti ń ṣe.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 5

Wo 1 Tẹsalóníkà 5:11 ni o tọ