1 Tímótíù 1:12 BMY

12 Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ẹni tí ó fún mi ní agbára, àní Kírísítì Jésù Olúwa wa, nítorí tí ó kà mí sí olóòótọ́ ní yíyànmí sí iṣẹ́ rẹ̀;

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 1

Wo 1 Tímótíù 1:12 ni o tọ