1 Tímótíù 1:13 BMY

13 Bí mo tilẹ̀ jẹ́ asọ̀rọ̀-òdì sí Ọlọ́run rí, àti onínúnibíni àti ìkà ènìyàn: ṣùgbọ́n mo rí àánú gbà, nítorí tí mo ṣe é nínú àìmọ̀ àti àìgbàgbọ́.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 1

Wo 1 Tímótíù 1:13 ni o tọ