1 Tímótíù 1:17 BMY

17 Ǹjẹ́ fún Ọba ayérayé, àìdíbàjẹ́, àìrí, Ọlọ́run kan ṣoṣo, ni ọlá àti ògo wà fún láéláé. Àmín.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 1

Wo 1 Tímótíù 1:17 ni o tọ