1 Tímótíù 1:18 BMY

18 Àṣẹ yìí ni mo pa fún ọ, Tímótíù ọmọ mi, gẹ́gẹ́ bí ìsọtẹ́lẹ̀ wọ̀nyí tó ó ti ṣáájú nípa rẹ̀, pé nípaṣẹ̀ wọ́n kí ìwọ lè máa ja ìjà rere;

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 1

Wo 1 Tímótíù 1:18 ni o tọ