1 Tímótíù 3:15 BMY

15 Ṣùgbọ́n bí mo bá pẹ́, kí ìwọ lè mọ̀ bí ó ti yẹ fún àwọn ènìyàn láti máa hùwà nínú ilé Ọlọ́run, tì í ṣe ìjọ Ọlọ́run, alààyè, ọ̀wọ́n àti ìpìlẹ̀ òtítọ́.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 3

Wo 1 Tímótíù 3:15 ni o tọ